baba o se
Oluwa l’olusoaguntan mi laye yio
Emi ki yoo s’alaini ohun to dara
O mu mi dubule ni papa oko tutu
O fun mi n’itura okan lat’ori ite
O mu mi lo n’ipa ona ododo, nitori or-u-ko-Re wa l’enu mi
Nitooto bi mo ti le rin lafonifoji
Ohun ki yoo fi mi si le fun ‘ sa oku
Ogo Re …………………………………….. Ogo Re
Ati opa Re………………………………….. Opa Re
Won tu mi ninu Oluwa tun nbo mi ……….O mbo mi
O fi mi yangan l’oju ota mi o ………………Ota mi
Tabili mi kun fun, ounje ayo ounje emi
O da ororo ayo si mi l’ori o
Ago mi si ng san f’ore ofe
Ire ati ayo yoo ma te le mi lehin
Tit’akuko yoo ko lehin omokunrin
Emi yoo si maa gbe ile Oluwa titi lai, nibe ni ayo onigbagbo wa o
I-le to dara to kun fun wara at’oyin o o
Paradise, ile ayo ilu ogo
Ogo Re …………………………………….. Ogo Re
Ati opa Re………………………………….. Opa Re
Won tu mi ninu Oluwa tun nbo mi ……….O mbo mi
O fi mi yangan l’oju ota mi o ………………Ota mi
Tabili mi kun fun, ounje ayo ounje emi
E yin Oluwa, ……………………………….Enyin Oluwa
Onigbagbo aye……………………………..Gbogbo onigbagbo aye
Tori p’Oluwa seun, ………………………..Oluwa seun laye wa
A o ma f’iyin fun …………………………..F’iyin f’Olu orun
Ma a se gbagbe ore Oluwa ………………..Iwo okan mi
Iwo okan mi ………………………………..E yin O O luwa
E ma yin Oluwa, orile ede gbogbo ………..Orile ede gbogbo
F’iyin fun Oluwa okan mi…………………
Nitori anu Re, duro! Titi! Lailai!
Ranti pe erupe lasan lo je
Imi Oluwa lo gbe o duro o
Se bi ologbon omo, ko f’imo ore han
F’ope fun Baba, tinu tinu re
Oju kan lo duro si to ng wo ise eda,
Emi aimore lo gbile ninu wa
A dabi itana eweko igbe ti o gbile
Iji fe koja lo, o dohun igbabge
Ranti pe erupe lasan lo je Erupe la’san
Imi Oluwa lo gbe o duro o Duro o
Se bi ologbon omo, ko f’imo ore han
F’ope fun Baba, tinu tinu re
Olorun iyin duro de O ni si oni, ati si O la o mu ileri ife
Duet Oluwa Olorun mi
Nigba mo ro ohun gbogbo pin, t’igbagbo mi saki
Iwo ko fi mi s’ile, Bi itana ipado, o to mi s’ona
Olorun mi, Iwo l’emi yoo ma yin
Gba’yin mi Baba gb’ope mi Gbo’pe mi
Gb’ope mi, t’ewo gba iyin mi ba ‘yin mi
Ojojumo l’ore Re si mi, Ose
Hallelujah o, s’Oba eri
Mo ti ni Jesu l’ore (227) (Instrumental Interlude)
He is a mighty God
He is a mighty God
Yahweh is a mighty God
He is a mighty God
Elshadai is a mighty God
He is a mighty God
All power bow before Him
Everybody bow before Him
Every kneel must fall before Him
Elohim is a mighty God
He is a mighty God
Adonai is a mighty God
He is a mighty God
Authorities bow before Him
He is a mighty God
Oso, Aje bow before Him
Ogbanje bow before Him
All demons bow before Him
Jehovah is a mighty God
He is a mighty God
Our God is a mighty God
He is a mighty God
The I AM is a mighty God
He is a mighty God
He sits enthroned in majesty,
Making unquestionable decisions.
Righteousness and Justice
Are the foundations of His throne
Pure light surrounds Him
While the earth is His footstool
Your ways Oh Lord are surely not our ways
You are a mighty God
Roots of evil hearken to His voice
He is a mighty God
Heavy hearts don’t be troubled
He is a mighty God
He is bigger than all your problems
He is bigger than any mountain
He is able to do and undo
Ati damilare, Modupeoluwa, O bunkum Ola mi, tori pe O femi
Ati damilare, Modupeoluwa, O bunkun Ola mi, tori pe O femi
Ati damilare o, mo-du-pe-ee, Iyanuoluwa po laye mi o, mo ki p’O seun
Ati damilare, Modupeoluwa, O bunkun Ola mi, tori pe O femi
Tori pe O fe mi, tori, pe O femi
Nitori pe O fe mi
Olu laanu mi, tori, p’O femi
Ayomide, tori, p’O femi
Ayomikun, tori, p’O femi
Iyanuoluwa po o, tori, p’O femi
Tori p’O femi ye, tori, p’O femi
Nitori p’O femi o ye ye, tori, p’O femi
Ati damilare, `Modupeoluwa, O bunkun Ola mi, tori pe O femi
Baba Mimo O se, mo yin O l’ogo o Baba
Eni to ba mo ‘nu ro, o ye ko m’ope da
Baba Mimo O se, mo f’ope fun O
Iyin ogo ni t’ire, a to ba j’aye o
Nigbat’ oro ba d’oju ru, Iwo l’ alaa tunse
Olu to s’ona, awon to ng ba rin ninu Emi
Ta lo ye ka f’iyin fun , biko ba se Oluwa,
Oluwa awon omo ogun
Ari iro ala Olorun Moose
Okan soso ajanaku o, ti ng m’igbo kiji kiji
Oluwa mi seun, Tori p’O femi
Eyin ara ninu Oluwa, ki lo de t’e fa’ju ro, te o bere mujo, te o ma miliki lo
Ab’Oluwa o seun ni, e ja ka f’imo ore han.
Baba O se O se
Jesu O se O se
Olorun Mimo O se
Oyigiyigi O se
Elerunihin O se
Awi mayehun O se
Eledumare O se
Alagbada Ina O se
Akoda Aye O Se
A seda Orun O Se
Alpha et Omega O se
Metalokan ijinle ife,
Baba Omo Emimimo
Mimo Mimo Mimo, Oluwa Olorun Eledumare Oba
Oba to da aye, ohun gbogbo ni sise
Mimo Mimo ninu Ola nla, Ko s’eni bi ire laye
A gbekele O, Maje k’oju ti wa
A ni igbagbo ninu Re o, Iwo ni Olorun,
Imole laarin okunkun aye, Ma s’amona wa
Eyin ara ninu Oluwa, ki lo ye Oga Ogo
Ki lo ye Atobiju, Ki lo ye Jesu wa
Kilo ye Baba Mimo Niwaju ite Re
Mimo Mimo, Mimo Mimo, Mimo Mimo lo ye O
Iwo la ba ma f’iyin fun Olorun Edumare