kokoro

Kini Kokore e o (Adura ni kokoro mi)
Kokoro wo lo ni l’owo (Adura ni kokoro mi)
Almighty formular f’onigbagbo (Adura ni kokoro mi)
Security Measures t’Oluwa fun wa (Adura ni kokoro mi)
Master key t’Oluwa se (Adura ni kokoro mi)
Eyi to ng ti ibi m’ole (Adura ni kokoro mi)
To ng s’ilekun ayo s’ile o (Adura ni kokoro mi)
Gba kokoro gbogbo n’ise re (Adura ni kokoro mi)
Eledumare l’O fi fun o (Adura ni kokoro mi)
O ti ko o b’oti le lo o (Adura ni kokoro mi)
Bere ohun gbogbo lowo Oluwa l’oruko Jesu moni yoo di si se (Adura ni kokoro mi)
Kokoro ile isura………ibi ewa onigbagbo (Adura ni kokoro mi)
Kokoro ibunkun gbogbo, (Adura ni kokoro mi)
t’on be ninu aye, Baba fi le mi lowo (Adura ni kokoro mi)
Gbogbo ‘lekun ibanuje (Adura ni kokoro mi)
l’oruko Jesu ni mo pa a lase (Adura ni kokoro mi)
Kema ti ke ma se si mo (Adura ni kokoro mi)
Fi kokoro e han mi o o o o o o o o (Adura ni kokoro mi)
kokoro agbara re (Adura ni kokoro mi)

(Adura ni kokoro mi)
E ko gbogbo iha mora Oluwa wo, e d’amure giri, giri, giri (Adura ni kokoro mi)
Nibo lo fi kokoro e si, (Adura ni kokoro mi)
iwo omo Olorun, (Adura ni kokoro mi)
Ma se ri talenti re m’ole (Adura ni kokoro mi)
Ma fi kokoro e to’le, (Adura ni kokoro mi)
jowo fi sise f’Oluwa (Adura ni kokoro mi)
Fi ran enikeji re lowo , (Adura ni kokoro mi)
Ma se si agbara re lo o (Adura ni kokoro mi)
Kini kokoro e o (Adura ni kokoro mi)
Ore dakun so fun mi kini kokoro e se….. (Adura ni kokoro mi)

en_USEnglish