ojojumo aye
Ologo to l’ogo o, o; Oluwa to ni ogo sa ma s’ogo lo
Ologo to l’ogo o, o; Oluwa to ni og sa ma s’ogo lo
Jesu mi to l’ogo o, Baba mi, Messiah to ni ogo, sa ma s’ogo lo
Se mi l’ogo o , o Baba mi, Oba to se Jabesi l’ogo, se mi l’ogo o
L’odo Re ni gbogbo ogo wa o, F’ohun jade lat’orun, se mi l’ogo
Oluwa Oluwa Oluwa orun on aye Iwo l’Oba to l’ogo, to n s’ogo o,
To n gbe ‘nu ogo Ologo Mimo Sir o, mo doable niwaju Re
Baba se mi l’ogo bo t se Ana l’ogo Baba se mi l’ogo bo ti se Jacobu l’ogo
Se mi logo o o, Olorun Ogo se mi l’ogo
Ologo to l’ogo o, o; Oluwa to ni og sa ma s’ogo lo
Baba Baba Baba Baba Baba l’oke ……………………. Baba
Baba Baba Baba Baba Baba l’oke Baba E se
Gbogbo aye mi ni ngo fi yin O Baba Baba E se
Gbogbo ohun to fi fun mi ni ng ma fin yin O Baba mi Baba E se
Modupe ore ana, modupe t’eni Baba Baba E se
Modupe t’ola ati t’ojo gbogbo Baba E se
Ore ti ko ni won, lat’ojo t’a ti bi mi Baba E se
Ogo Oluwa o tan s’ori mi Baba E se
O f’anu Yimika, modupe to Damilare Baba E se
Baba E se, ore t’E se fun mi Baba E se
Anu yin ma po ninu aye mi o Baba E se
Ore yin ma po l’ori ise mi o Baba E se
Baba Bababa Baba Baba l’oke Baba E se
Ba Ba Ba Ba Baba mi o Baba E se
Babababa Baaaa, Babababa Baaaa, Babababa Baba mi o, E se Ese
Paradise lo wu mi o ki ng ba won gbe
Orun rere lo wu mi o, ki n ba won lo o
Orin bi ti Dafidi wu mi o, Baba fun mi ko
Ogbon bi ti Solomon wu mi o, Baba fun mi ni o
Igbabgo bi t’Abraham wu mi o, Baba gbe mi wo
Omo bi Samuel wu mi o, Baba fun mi bi o
Baba, L’aye ti mo wa ki ng ma s’ase danu
K’Owo omo alafia ko ma se won mi
Ki ng t’egbe, Ki ng t’ogba, Ki ng ri ba ti se
Ki ng r’oju r’aye sin O o, titi aye mi
Oluwa se wonyi fun mi, ki n le dupe ore
Baba seyi fun mi, ki n le dupe ore Re
Oluwa fi mi s’example, k’aye le mo E l’Olorun
Ni oruko Jesu, O ma juna ju se – Ni oruko Jesu, O ma juna ju se
Ore so ngbo ‘ro mi dada
Ore so ngbo ‘ro mi dada
Mo gbe ‘jo Jesu de e bere m’ole ka jo jo
‘Tori ijo Jesu yato s’ijo palongo
ijo Jesu yato s’ijo palongo
T’emi ba tin yin Baba – k’e yin na follow
Ko gb’owo ko gb’obi – iyin atope lo require o
Mo yin O, (Jesu)
O ma se (Jesu)
Oba ti ngelese (Iwo sa l’ope ye)
O fun mi layo (O so mi d’asegun)
O fun mi ni’reti (O se mi l’ogo)
Ai de ni yin Jesu (iyen ku s’owo e)
Ai de ni yin Jesu (iyen ku s’owo e)
T’emi ba tin yin Baba (k’e yin na follow)
Moni k’e yin na, (jo, jo, jo)
E k’alleluyah o, (s’Olorun l’oke Baba, s’Olorun l’oke Omo, s’Olorun l’oke Emi Mimo)
Omode s’ese oro lai ni’gbagbo (O lo sa sinu igbo, o f’abere b’oju)
Se mope o n tan ra e naa ni
O je sa to Jesu, (Ohun ma l’Oluwa o)
O je sa to Jesu, (Ohun ni Messaiah o, Enito d’opo Jesu mu lo le r’igbala ayeraraye)
A a a a oro ni
Sa ti gba Jesu s’aye e ko born again (‘Tori, Baba mi ti so ninu iwe mimo)
Ohun o f’eku elese (Afi ko ronupiwada)
O je ya gba Jesu (Ko le ri joba Baba mi)
O n yoyo, (Yoyo l’on yo, angel devil won dunnnu, Esu gangan wa nmu ‘jo)
Esu ma yo mo (Jesu Kristi si ma de)
Esu ma yo mo (Jesu Kristi ma mbo wa o)
Esu ma yo mo (Jesu Kristi wa ni corner)
Esu ma yo mo (Jesu Kristi ti de tan)
A a a a a Oro ni
E f’ope at’iyin f’Eledumare, (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Ef’ope at’iyin f’Eledumare e gbega (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
E’ope fun, e f’iyin fun, e f’ogo fun, e b’ola fun Baba Mimo (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Ore t’O se fun mi, O po yeye (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Ore t’O se fun mi I Baba ko ma lonka (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Ma f’orin yin O, Ma f’ijo yin O (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
‘Toripe Iwo l’Oba, Oba l’ori aye gbogbo, (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Ef’ope at’iyin f’Eledumare e e e o (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Olorun Oba Oba ti nf’oba je (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Ologo didan, Oba to j’oba lo (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Oba Alagbara, Ogbamu gbamu oju orun o se e gbamu (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Okiki okaka okiki, Oba ti ng ki ‘mo l’aya (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Emi ni ma se beru (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Kiki ‘mole, kiki ogo, kiki ola, (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
T’O ba seju peren, monamona a ko, ara a tele, aye a wariri (E gbe ga – Ore t’O se l’aye mi po repete)
Ojojumo aye o ni ngo ma yin O l’ogo o (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Oba mi ti ngbe ‘nu afefe, pitu arambara bi ojojo arakuro (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Kabi o O ma si o Eledumare Oba alase (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Mimo Mimo ninu ola nla, (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Oba to n wo mimo, to n se mimo, to n mu mimo, to je mimo, to n gbe ‘ibi mimo (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Eleburu ike Ato farati bi oke (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
O fi gbogbo orun s’ele ka le mo titobi ola nla Re (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Iwo l’Adagba ma t’epa ojo, adagba ma paro oye (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Obirikiti Oba to gbe ‘ku mi laaye (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Okan soso ajanaku ti ng mi’gbo kiji kiji (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Ojowu jowu Oba ti ng je Emi ni mase beru (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Ola nla lo wo l’aso, Ogo l’aso ileke E o (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Alagbada ina, Alawo tele orun (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Ojojumo aye, ojojumo aye, o o o (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Ojojumo, ojojumo, ojojojumo aye mi (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)
Ojojumo aye from dusk to dawn (Ojojumo aye o ni ngo ma f’ogo f’Oluwa)